OLÓLÙFẸ́ RONALDO D’OJU IKÚ NI MI – Davido

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Daniel Ayomiposi Oluwamuyide, Sango-Ọta | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́rú, 29, Oṣù Keje 2026. 

 

 

Afrobeats Superstar, David Adedeji Adeleke ti gbogbo aye mọ si Davido ti kede ni gbangba pe oun jẹ ololufẹ Cristiano Ronaldo to gaju, ati pe oun ati CR7 maa n ba ara wọn sọrọ nigbagbogbo lori foonu.

 

Ninu ifọrọwanilẹnuwo kan ti o ṣe laipẹ yii, OBO sọ pe: “I’m a die-hard Ronaldo fan, we chat regularly” – ti o tumọ si “Mo jẹ ololufẹ Ronaldo ti o le koko, a ma n ba ara wa sọrọ nigbagbogbo.”

 

ÌWÁDÌÍ OJB NEWS:

Davido, ti o jẹ ọmọ bibi Atlanta ṣugbọn ti o dagba ni Eko, ti safihan screenshot kekere kan ninu chat rẹ pẹlu Ronaldo nibi ti wọn ti n ṣe asọye lori bọlu ati orin.

ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ 

*Sunday Adeyemo ṣe ìfilọ́lẹ̀ Irú Ekun Security Network nilu Osogbo

SUNDAY IGBOHO S’ABEWO S’ILUU OSOGBO LÁTI ṢE ÌFILỌ́LẸ̀ IRÚ ẸKÙN SECURITY NETWORK

Ọpọlọpọ awọn ololufẹ Davido ni wọn ti n dahun, diẹ ninu wọn ni Messi ni ẹni ti o dara ju, ṣugbọn Davido tẹnumọ pe Ronaldo ni GOAT rẹ.

 

Ibasepọ laarin awọn agba orin Afrobeats ati awọn agbabọọlu nla ti n pọ si, ati eyi fihan bi ere idaraya ati ere orin ṣe n papọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

OJB MEDIA HUB is a premier online news platform delivering accurate, timely and unbiased new accross Nigeria and the world.