Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Daniel Ayomiposi Oluwamuyide, Sango-Ọta | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́ Aiku , 16, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410
Ilukulu bii Ejo Aije ni wọn lu ẹgbẹ agbaboolu Manchester City l’osan-an oni – Wọn ti gba goolu Community Shield!
Ẹgbẹ agbaboolu Arsenal ti fihan pe wọn ti ṣetan fun saa tuntun yii lẹhin ti wọn fọ Manchester City lulẹ pẹlu 3-0 ninu ifẹsẹwọnsẹ Community Shield to waye l’osan-an oni.
Bi Ere Ṣe Lọ:
1′ – R. Calafiori – Goal ni iṣẹju àkọkọ
28′ – K. Havertz – Goal ni iṣẹju 28
48′ – M. Odegaard – Goal ni iṣẹju 48
Arsenal 3 – 0 Manchester City
Ilukulu nla ni, awọn ọmọ Arsenal ko fun City ni aye rara – wọn ṣẹgun wọn gẹgẹ bi ẹni pe ẹgbẹ kekere ni.
ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ
Bayi Arsenal ti gba ife Community Shield 2025 – eyi ni ami pe wọn fẹ ja fun Premier League lọdun yii!
OJB News Yoruba yoo maa mu gbogbo iroyin ere idaraya wa fun yin ni ede Yoruba.
