Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Abuja | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ Iṣẹgun, 1, Oṣù Kẹ̀sán 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410
Nínu oṣù karùn-ún ọdún 2026, eyii ni bí àwọn ipinlẹ merindinlogoji àti olú ìlú orile-ede yii, Abújá ṣe gba owó sì láti ọwọ ijọba apapọ orile-ede Naijiria yìí, ipinlẹ Èkó lo ń lé iwájú bayi nígbà tí ipinlẹ Delta tẹ́lẹ̀, bẹẹni ipinlẹ Rivers wá nípò kẹta tí Bayelsa sì kẹrin Akwa-Ibom losi karùn-ún tí ipinlẹ Kano wá nípò kẹfà.
Ẹ jẹ ki kí a kà àwọn ipinlẹ to n gbọ́ woju lọ ní isale yìí

1. Lagos — Gross ₦362.86bn — Net ₦320.09bn
2. Delta — Gross ₦327.49bn — Net ₦275.09bn
3. Rivers — Gross ₦270.61bn — Net ₦267.59bn
4. Bayelsa — Gross ₦244.85bn — Net ₦221.84bn
5. Akwa Ibom — Gross ₦241.45bn — Net ₦218.25bn
6. Kano — Gross ₦133.35bn — Net ₦126.34bn
7. Oyo — Gross ₦131.08bn — Net ₦116.13bn
8. Ondo — Gross ₦101.46bn — Net ₦96.11bn
9. Abia — Gross ₦100.26bn — Net ₦86.05bn
10. Kaduna — Gross ₦99.17bn — Net ₦79.85bn
11. Imo — Gross ₦97.34bn — Net ₦89.61bn
12. Benue — Gross ₦97.12bn — Net ₦86.15bn
13. Edo — Gross ₦96.74bn — Net ₦84.03bn
14. Borno — Gross ₦95.25bn — Net ₦90.04bn
15. Jigawa — Gross ₦95.22bn — Net ₦84.82bn
16. Katsina — Gross ₦94.94bn — Net ₦78.94bn
17. Anambra — Gross ₦92.76bn — Net ₦88.13bn

18. Sokoto — Gross ₦88.39bn — Net ₦83.85bn
19. Niger — Gross ₦87.96bn — Net ₦81.21bn
20. Plateau — Gross ₦87.38bn — Net ₦76.32bn
21. Kebbi — Gross ₦86.29bn — Net ₦82.62bn
22. Zamfara — Gross ₦85.39bn — Net ₦79.24bn
23. Taraba — Gross ₦84.32bn — Net ₦79.46bn
24. Kogi — Gross ₦83.99bn — Net ₦80.94bn
25. Adamawa — Gross ₦82.82bn — Net ₦81.16bn
26. Enugu — Gross ₦81.89bn — Net ₦78.34bn
27. Yobe — Gross ₦81.89bn — Net ₦77.18bn
28. Bauchi — Gross ₦81.22bn — Net ₦77.57bn
29. Nasarawa — Gross ₦79.13bn — Net ₦70.61bn
ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ:
Ile eko tá ń pè ní ìgbéyàwó: Diẹ loku kí n fi ẹ̀kọ́ odi bá ìgbéyàwó mi jẹ́…….
30. Kwara — Gross ₦77.28bn — Net ₦72.17bn
31. Osun — Gross ₦76.53bn — Net ₦70.77bn
32. Gombe — Gross ₦75.85bn — Net ₦70.05bn
33. Ebonyi — Gross ₦75.30bn — Net ₦70.43bn
34. Ogun — Gross ₦74.98bn — Net ₦64.71bn
35. Cross River — Gross ₦72.06bn — Net ₦57.54bn
36. Ekiti — Gross ₦70.30bn — Net ₦63.85bn
