Orísun: OJB News Yorùbá | Akọroyin: Taofeek Ajala | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọbọ, 29, 2026
Ikọ Chelsea ti fọ apamọwọ wọn, wọn ti pari ere idaraya £117 million kan lati kó ọmọ England, Morgan Rogers dani lọwọ Aston Villa.
Gẹgẹ bi BBC se wi ni ọjọ Abamẹta yi, owo yi ti di owo ti o ga ju ti Chelsea ti san ri ninu itan wọn lọ. Ko si elomiran ti wọn ti ra gbowolori to bayi.
O tun di ami tuntun fun gbogbo England – ko si agbabọlu ọmọ England ti o ti gbowolori to Rogers bayi!
Kini ninu adehun na?
Ọmọ ọdun 23 ọdun na yoo kọwe adehun ọdun mẹfa, Chelsea si ni anfaani lati fi ọdun kan kun.
Oun yoo de London fun ayẹwo ara ni ọjọ Aje, leyin ti o ba pari iṣẹ orile-ede England ninu World Cup to n lọ lọwọ yi.
Owo £117m yi ju £116m ti Man City fi ra Elliot Anderson lọ, o si ju £107m ti Chelsea ra Enzo Fernandez ni 2023 lọ.
Lati ọmọ ile-ẹkọ Man City, to lọ si Middlesbrough, bayii o ti di olori lọwọ Unai Emery ni Villa – 21 goals ninu ere 85, o si gbe Europa League.
Xabi Alonso ti de ori aga Chelsea bayi, o si ti n kọ ikọ tuntun. Rogers ni star akọkọ rẹ!
Chelsea ti ṣetan lati jó o!
