ÈYÍ NI ÀWỌN ÌPÍNLẸ̀ TO N GBOWÓ JULỌ LÁTI ỌDỌ IJỌBA APAPỌ NÀÌJÍRÍÀ L’OSU KARÙN-ÚN

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Abuja | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ Iṣẹgun, 1, Oṣù Kẹ̀sán 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410

 

 

Nínu oṣù karùn-ún ọdún 2026, eyii ni bí àwọn ipinlẹ merindinlogoji àti olú ìlú orile-ede yii, Abújá ṣe gba owó sì láti ọwọ ijọba apapọ orile-ede Naijiria yìí, ipinlẹ Èkó lo ń lé iwájú bayi nígbà tí ipinlẹ Delta tẹ́lẹ̀, bẹẹni ipinlẹ Rivers wá nípò kẹta tí Bayelsa sì kẹrin Akwa-Ibom losi karùn-ún tí ipinlẹ Kano wá nípò kẹfà.

Ẹ jẹ ki kí a kà àwọn ipinlẹ to n gbọ́ woju lọ ní isale yìí

Aare Bola Ahmed Tinubu rèé to fi ọwọ lẹ ràn-án tó ń wo ìṣe àwọn òṣèlú alátakò

1. Lagos — Gross ₦362.86bn — Net ₦320.09bn

2. Delta — Gross ₦327.49bn — Net ₦275.09bn

3. Rivers — Gross ₦270.61bn — Net ₦267.59bn

4. Bayelsa — Gross ₦244.85bn — Net ₦221.84bn

5. Akwa Ibom — Gross ₦241.45bn — Net ₦218.25bn

6. Kano — Gross ₦133.35bn — Net ₦126.34bn

7. Oyo — Gross ₦131.08bn — Net ₦116.13bn

8. Ondo — Gross ₦101.46bn — Net ₦96.11bn

9. Abia — Gross ₦100.26bn — Net ₦86.05bn

10. Kaduna — Gross ₦99.17bn — Net ₦79.85bn

11. Imo — Gross ₦97.34bn — Net ₦89.61bn

12. Benue — Gross ₦97.12bn — Net ₦86.15bn

13. Edo — Gross ₦96.74bn — Net ₦84.03bn

14. Borno — Gross ₦95.25bn — Net ₦90.04bn

15. Jigawa — Gross ₦95.22bn — Net ₦84.82bn

16. Katsina — Gross ₦94.94bn — Net ₦78.94bn

17. Anambra — Gross ₦92.76bn — Net ₦88.13bn

Akojopo diẹ àwòrán àwọn gómìnà to n gba owó julọ latodo ìjọba apapọ

18. Sokoto — Gross ₦88.39bn — Net ₦83.85bn

19. Niger — Gross ₦87.96bn — Net ₦81.21bn

20. Plateau — Gross ₦87.38bn — Net ₦76.32bn

21. Kebbi — Gross ₦86.29bn — Net ₦82.62bn

22. Zamfara — Gross ₦85.39bn — Net ₦79.24bn

23. Taraba — Gross ₦84.32bn — Net ₦79.46bn

24. Kogi — Gross ₦83.99bn — Net ₦80.94bn

25. Adamawa — Gross ₦82.82bn — Net ₦81.16bn

26. Enugu — Gross ₦81.89bn — Net ₦78.34bn

27. Yobe — Gross ₦81.89bn — Net ₦77.18bn

28. Bauchi — Gross ₦81.22bn — Net ₦77.57bn

29. Nasarawa — Gross ₦79.13bn — Net ₦70.61bn

ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ:

Ile eko tá ń pè ní ìgbéyàwó: Diẹ loku kí n fi ẹ̀kọ́ odi bá ìgbéyàwó mi jẹ́…….

Bí idibo gbogboogbo ọdún 2027 ṣe kú diẹ, àjọ INEC ṣe agbeyewo fún ìgbáradì ibo ṣáájú ọdún 2027, eyii ni òun ti ṣẹlẹ̀ nibẹ….

30. Kwara — Gross ₦77.28bn — Net ₦72.17bn

31. Osun — Gross ₦76.53bn — Net ₦70.77bn

32. Gombe — Gross ₦75.85bn — Net ₦70.05bn

33. Ebonyi — Gross ₦75.30bn — Net ₦70.43bn

34. Ogun — Gross ₦74.98bn — Net ₦64.71bn

35. Cross River — Gross ₦72.06bn — Net ₦57.54bn

36. Ekiti — Gross ₦70.30bn — Net ₦63.85bn

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

OJB MEDIA HUB is a premier online news platform delivering accurate, timely and unbiased new accross Nigeria and the world.