ỌBA K’ỌBA TO BA DÁ SỌ̀RỌ̀ ÒṢÈLÚ, YÓÒ JẸ’YAN RẸ N’IṢU – Gomina Makinde

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Muyideen Akinro, Ìbàdàn | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ Aiku, 6, Oṣù Kẹ̀sán 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410

 

 

IBARAPA, OYO STATE – Gomina ipinlẹ Oyo, Engr. Seyi Makinde, ti kilọ fun awọn Oba alaye ni ipinlẹ Oyo lati yago fun didasi si oṣelu aṣoju bi akoko ipolongo ibo 2027 ṣe n sunmọ.

Makinde sọ ọrọ yii loni-in nigba ti o lọ gba oye Aare Asoludero ti Ibarapaland ni ayẹyẹ nla ti o waye ni Ibarapa.

ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ:

Láyé Sanni Abacha, eyii ni bí wọn ṣe tán Olóògbé MKO Abiola kúrò ní Nàìjíríà àti bí wọn ṣe de àwọn agbanipa sì….

Gomina naa sọ pe oun ti kilọ fun awọn Oba tẹlẹ lati “fi owo si ibi ti owo n gbe” ati lati ṣe gbogbo oloselu ni ọmọ wọn lai ṣe ojuṣaaju.

Ṣugbọn o tẹnumọ pe bi Oba kan ba pinnu lati da si oṣelu ni gbangba lati ṣe atilẹyin fun ẹgbẹ kan bi ipolongo ba bẹrẹ, ijọba rẹ yoo bu iru Oba bẹẹ.

“Ẹyin Kabiyesi, ẹ jẹ baba fun gbogbo wa. Ẹ máṣe jẹ ki ẹnikẹni lo yin fun oṣelu idọti. Ti ẹ ba da si oṣelu, a maa sọ otitọ si yin.”

Ayẹyẹ Aare Asoludero naa kun fun awọn olori ilu, awọn Oba, ati awọn oloṣelu pataki ni Oyo.

Gomina Seyi Makinde nígbà tí wọn ń jawe òye Asoludero le lori nilu Ibarapa

ENGLISH TRANSLATION (BELOW FOR OJB NEWS YORUBA INTERNATIONAL AUDIENCE):

 

MAKINDE WARNS TRADITIONAL RULERS: DON’T TAKE SIDES IN 2027 CAMPAIGNS, WE WILL CALL OUT ANY OBA WHO DOES!

 

The Governor of Oyo State, Engr. Seyi Makinde, has warned traditional rulers in Oyo State to stay away from partisan politics as the 2027 election campaigns draw closer.

 

Makinde made this statement today while receiving the chieftaincy title of Aare Asoludero of Ibarapaland at a grand ceremony held in Ibarapa.

 

The Governor said he had previously advised the Obas to “put their money where their mouth is” in terms of neutrality and to treat all politicians as their children without favouritism.

Gómìnà Seyi Makinde nile Ìjọba ipinlẹ Ọyọ

However, he emphasized that if any Oba decides to openly dabble into politics to support a particular party when campaigns begin, his administration will openly call out such a monarch.

“Your Majesties, you are fathers to all of us. Don’t allow anyone to use you for dirty politics. If you dabble into politics, we will tell you the truth.”

The Aare Asoludero ceremony was attended by community leaders, traditional rulers, and top politicians in Oyo State.

 

#OJBNewsYoruba #SeyiMakinde #Ibarapa #OyoState #AareAsoludero #2027Election #YorubaNews

2 thoughts on “ỌBA K’ỌBA TO BA DÁ SỌ̀RỌ̀ ÒṢÈLÚ, YÓÒ JẸ’YAN RẸ N’IṢU – Gomina Makinde

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

OJB MEDIA HUB is a premier online news platform delivering accurate, timely and unbiased new accross Nigeria and the world.