Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olatunde Alága, Sango-Ọta | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ Àìkú, 6, Oṣù Kẹ̀sán 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410
Oluyole Warriors ti Ibadan ti ṣe ipada itan si bọọlu Africa lẹhin ọdun mẹta ti wọn ko si! Ni MKO Abiola Sports Arena, Abeokuta ni ọjọ Saturday, wọn lu CS Sfaxien ti Tunisia 1-0 ninu CAF Confederation Cup First Preliminary Round.
ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ:
Ọba k’oba yòówù tí ó bá dá sí ọrọ òṣèlú yóò jẹ iyàn rẹ n’isu – Gómìnà Seyi Makinde
Akoko pataki: iṣẹju kerindinlogbon ni Emmanuel Lucky gba ayo wo inu apoti o fi ọgbọn fi bọọlu sinu àwọn Sfaxien!
CS Sfaxien tẹ siwaju ni idaji keji, ṣugbọn olugbeja Shooting Stars duro ṣinṣin.

Ipele tí ó tẹle?
Ipele ere keji yoo ṣoro diẹ fun Shooting Stars – Sfaxien yoo ni anfani ile ni Sfax, Tunisia ni ọjọ ìsinmi Sunday, ọjọ kẹtàlá 13, oṣu Kẹ̀sán, wọn yoo fẹ lati figa gbaga ni abala kejì ìdíje naa.
Fun Shooting Stars sibẹsibẹ, iṣẹgun yii fun wọn ni igbelaruge pataki bi wọn ṣe n tẹsiwaju ipada pipẹ wọn si bọọlu ẹgbẹ Africa.
Oluyole Warriors yoo nireti lati pari iṣẹ naa ni Tunisia ki wọn tẹsiwaju ninu idije naa.
OLUYOLE FAKO YỌ ! Shooting Stars ti Ibadan bẹrẹ igbega Africa pẹlu iṣẹgun 1-0 lori Tunisia CS Sfaxien nilu Abeokuta! Emmanuel Lucky lo gba goolu ni iṣẹju 26. Lẹhin ọdun 26 (1999), 3SC padà sórí ẹsẹ wọn ! Ere keji ni Tunisia ni Sept 13 yoo le! Ṣe Oluyole yoo tẹsiwaju?
