INÁ MONAMONA ORILẸ-EDE NÀÌJÍRÍÀ YOO DÁRA SÍ JU BAYI LỌ LÁÀRIN ỌJỌ́ MẸTA PÉRÉ – Tegbe

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Abuja | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́ Àbameta 7, Oṣù Kọkànlá 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410

 

Pe Arike’s and More gẹgẹ bi alase oúnjẹ ìgbàlódé fún òde àríyá rẹ

 

*Iná mànàmáná yóò dára sí i láàárín wákàtí 72 — Mínísítà

 

 

Bí ọ̀rọ̀ ìpèsè ina ọba ṣe di dákú daji láàárín ìlú eyii lo mú Mínísítà fún ọ̀rọ̀ Iná Mànàmáná, Joseph Tegbe, ti sọ pé ìpèsè iná mànàmáná yóò bẹ̀rẹ̀ sí dára sí i láàárín wákàtí mejidinlaadota sì mejilelaadorin. 48 sí 72.

 

Mínísítà náà sọ èyí nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ nípa ìṣòro iná mànàmáná tó ti ń ṣẹlẹ̀ ní àwọn apá kan ní orílẹ̀-èdè náà ní àwọn ọjọ́ díẹ̀ sẹ́yìn.

Minisita fún ọrọ iná monamona, Ọgbẹni Joseph Tegbe

Ó sọ pé Ìjọba Àpapọ̀ ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ láti yanjú àwọn ìṣòro tó ń dí iná lọ́wọ́, pàápàá jùlọ nípa bí a ṣe ń ṣe iná náà, àti bí a ṣe ń gbé e kọjá sí àwọn ibì kan sì ibi kan.

 

Gẹ́gẹ́ bí ó ṣe sọ, àwọn ìṣòro wọ̀nyí ni ó fa ìkùnà iná àti ìgé iná tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ará ìlú ti ń rí ní àìpẹ́ yìí.

Tegbe rọ àwọn ará Nàìjíríà láti ṣe sùúrù díẹ̀, ó sì ṣèlérí pé ìgbésẹ̀ tí ìjọba ń gbé yóò mú ìyàtọ̀ wá láìpẹ́.

ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ:

Ara meeriri ó, Yẹmi My Lover tí da padà fún Tope Alabi pé “A jẹ pe ọtí Jésù lo ń pá ẹ” kín lo fa awuyewuye láàrin àwọn méjèèjì yí. *Bẹẹ lónìí “Ìyàwó mi ni Tope Alabi tẹ́lẹ̀ kò to sá lọ…” Nibo ni Tope salọ, Ta ló gbà Tope Alabi mọ Yemi My Lover lọ́wọ́ óò. Kaa síwájú àti síwájú sí lórí ìkànnì ayelujara OJB Medias Hub.

 

Ó tún sọ pé ìjọba kò ní sinmi títí tí ìpèsè iná mànàmáná yóò fi dúró ṣinṣin, tí ó sì fi dára sí i ju bí ó ti rí lọ.

One thought on “INÁ MONAMONA ORILẸ-EDE NÀÌJÍRÍÀ YOO DÁRA SÍ JU BAYI LỌ LÁÀRIN ỌJỌ́ MẸTA PÉRÉ – Tegbe”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

OJB MEDIA HUB is a premier online news platform delivering accurate, timely and unbiased new accross Nigeria and the world.