ÈYÍ NI ÌGBÀ KEJE TÍ ATIKU YÓÒ DÍJE FUN IPÒ ÀÀRẸ ORILE-EDE NAIJIRIA, YÓÒ WỌLÉ NI, ÀBÍ YOO TÚN LU’LẸ

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Abuja | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ Ẹti, 5, Oṣù Kẹ̀sán 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410

 

 

Ó ti dije fun ipo aarẹ ni igba mẹfa tẹlẹ, o ti padanu idibo gbogbogbo mẹta gẹgẹ bi oludije ati primaries mẹta gẹgẹ bi olufojusi. Bayi o n ṣe igbiyanju keje ṣaaju 2027.

Olóyè Atiku Abubakar àti Ọ̀gá rẹ Olóyè Olusegun Obasanjo

Àkójọpọ̀ itan Atiku lẹ́nu erongba rẹ láti di Ààrẹ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà:

1. 1992-1993 — Igbiyanju akọkọ (SDP): Primaries ni Jos, padanu si Abiola (3,617) ati Kingibe (3,255), Atiku ni 2,066. Ibẹrẹ ije ọdun 30.

 

2. 2007 — Keji / Akọkọ lori iwe idibo (AC): INEC kọkọ yọ ọ kuro, ile-ẹjọ giga gba a pada ni April 16 2007. Wa ni ipo kẹta pẹlu 7% (2.6m votes) lẹhin Yar’Adua ati Buhari.

 

3. 2011 — Kẹta (PDP): Northern Consensus Candidate, padanu si Jonathan — Jonathan 2,736 vs Atiku 805.

ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ:

Komisanna fún èrè ìdárayá ni ipinlẹ Èkó, Lekan Fatodu ṣe àwárí ọmọ àti iyá tí àwọn òṣìṣẹ́ Ka’nsu dina mọ…..

4. 2015 — Kẹrin (APC): Primaries ni Lagos Dec 2014, padanu si Buhari — Buhari 3,430, Kwankwaso 974, Atiku 954.

 

5. 2019 — Karun / Keji lori iwe (PDP): Bori primaries ni Port Harcourt pẹlu 1,532 votes, padanu si Buhari nipasẹ ju 3 million votes.

 

6. 2023 — Kẹfa / Kẹta lori iwe (PDP): Bori ni Abuja pẹlu 371 vs Wike 237, padanu si Tinubu (APC).

 

7. 2027 — Keje (ADC): Lẹhin ti o kuro ni PDP ni 2025, o bori tiketi ADC ni May 2026, o lu Amaechi. O sọ pe 2027 yoo jẹ igbiyanju ikẹhin rẹ.

 

Ibeere: Ṣe igbiyanju láti díje fún ìgbà keje ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ṣe yóò wọlé ní abi yóò tún lu’lẹ̀ fún ìgbà keje nínú ìbò gbogboogbo lọdun 2027?

 

#OJBNewsYoruba #Atiku #2027Election #ADC #PDP #IroyinPajawiri #Naijiria

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

OJB MEDIA HUB is a premier online news platform delivering accurate, timely and unbiased new accross Nigeria and the world.