Ó tán ó! SUNDAY IGBOHO NAA BÁWỌN KÒ PA NÍBI ASEKAGBA ÌPOLONGO FÚN BỌLÁ OYEBAMIJI NI ÌPÍNLẸ̀ ỌṢUN

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Bolarinwa Wasiu, Ọṣun | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́ Ẹti 14, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410

 

Agbara nla lo sele loni ni ilu Osogbo, ipinle Osun, bi a ṣe ri ajijagbara omo Yoruba, Chief Sunday Adeyemo Igboho, ti o wa nibi ipolongo igbeyin fun oludije sipo gomina labẹ ẹgbẹ APC, Bola Oyebamiji (AMBO).

ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ 

Àwọn àjọ eleto ibo tí pín àwọn ohùn èlò idibo káàkiri ipinlẹ Ọṣun lónìí….

Sunday Igboho ti o wọ aṣọ funfun, ti o n fi ami isegun meji han, fi ayọ han niwaju awon ololufẹ rẹ. Wiwa rẹ ni ibi ipolongo naa ti fa ariwo nla laarin awon eniyan.

Awon oloye egbe APC ati awon omo egbe naa tun wa nibe, ti won n fi atilẹyin han fun AMBO.

Eyii ni òun ti àwa mọ nípa ẹjọ́ tí wọn ní Atiku Abubakar pé Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu lórí ìwé ẹri agunbaniro NYSC nile ẹjọ́…

OJB News Yoruba yoo mu alaye kikun wa fun yin laipe.

 

Kini ero yin si wiwa Sunday Igboho ni Osogbo yii? E sọ o di mimọ ni isalẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

OJB MEDIA HUB is a premier online news platform delivering accurate, timely and unbiased new accross Nigeria and the world.